ỌGBẸ́ ỌKÀN MI
Rédíò Afínjú Rédíò Afínjú
92 subscribers
2 views
0

 Published On Streamed live on Sep 19, 2024

ỌGBẸ́ ỌKÀN MI pẹ̀lú Samuel Oladayo

Òkú kìí f’arapamọ́ f’ẹ́ni tí yoó sín. Ẹ sún mọ́ wa níhà’hín, kẹ́ẹ sọ gbogbo ohun tí baá ń dún yín l’ọ́kàn, yálà l’órí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ ni àbí àwọn míràn.

You can reach our studios on 09121111115. You can also contact our marketing department on 09111000035.

show more

Share/Embed